Jeremáyà 23:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ rẹ̀ ni a ó gba Júdà là,Ísírẹ́lì yóò sì máa gbé ní aláìléwuÈyí ni orúkọ tí a ó fi máa pè é: Olúwa Òdodo wa.

Jeremáyà 23

Jeremáyà 23:2-9