Jeremáyà 23:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó wá olùṣọ́ àgùntàn fún wọn, tí yóò darí wọn, wọn kì yóò bẹ̀rù tàbí dààmú, bẹ́ẹ̀ ni ọ̀kan kì yóò sọnù,” ni Olúwa wí.

Jeremáyà 23

Jeremáyà 23:1-10