Jeremáyà 2:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ̀yin ìran yìí, ẹ kíyèsí ọ̀rọ̀ Olúwa:“Àbí ilẹ̀ ńlá olókùnkùnkí ló dé tí àwọn ènìyàn mi ṣesọ wí pé, ‘A ní àǹfààní látimáa rìn kiri? A kò sì ní wá sọ́dọ̀ rẹ mọ́?’

Jeremáyà 2

Jeremáyà 2:27-36