Jeremáyà 2:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nínú aṣán mo fìyà jẹ àwọnènìyàn yín, wọn kò sì gbaìbáwí, idà yín ti pa àwọnwòlíì yín run, gẹ́gẹ́ bíkìnnìún tí ń bú ramúramù.

Jeremáyà 2

Jeremáyà 2:27-31