Jeremáyà 2:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wúndíá ha le gbàgbé ohunọ̀ṣọ́ rẹ̀ bí, tàbí ìyàwó ha le gbàgbé ohunọ̀ṣọ́ ìgbéyàwó rẹ̀? Síbẹ̀, àwọnènìyàn mi ti gbàgbé mi ní ọjọ́ àìníye.

Jeremáyà 2

Jeremáyà 2:27-36