Nítorí náà, jẹ́ kí ìyàn mú ọmọ wọnjọ̀wọ́ wọn fún ọwọ́ idàjẹ́ kí ìyàwó wọn aláìlọ́mọ àti opójẹ́ kí a pa àwọn ọkùnrin wọnkí a sì fi idà pa àwọn ọdọ́mọkùnrinwọn lójú ogun.