Jeremáyà 18:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣe kí a fi rere san búburú?Síbẹ̀ wọ́n ti gbẹ́ kòtò fún mi,rántí pé mo dúró níwájú rẹ,mo sì sọ̀rọ̀ ní torí wọn, látiyí ìbínú rẹ kúrò lọ́dọ̀ wọn.

Jeremáyà 18

Jeremáyà 18:12-23