Jeremáyà 18:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí a gbọ́ ohùn ẹkún láti ilé wọnnígbà tí ó bá mu àwọn jagunjagunkọ lù wọ́n lójijì nítorí wọ́n ti gbẹ́kòtò láti mú mi. Wọ́n ti dẹ ìkẹkùn fún ẹṣẹ̀ mi

Jeremáyà 18

Jeremáyà 18:14-23