Jẹ́nẹ́sísì 7:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo wọn wọlé ní takọ tabo bí Ọlọ́run ti pàṣẹ fún Nóà, Olúwa sì tì wọn mọ́ inú ọkọ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 7

Jẹ́nẹ́sísì 7:7-20