Jẹ́nẹ́sísì 7:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òjò náà sì rọ̀ ní àrọ̀ìrọ̀dá fún ogójì ọ̀sán àti ogójì òru, ọkọ̀ náà sì ń léfòó lórí omi, kúrò lórí ilẹ̀ bí omi náà ti ń pọ̀ sí i.

Jẹ́nẹ́sísì 7

Jẹ́nẹ́sísì 7:12-21