Jẹ́nẹ́sísì 7:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Méjìméjì ni gbogbo ẹ̀dá tí ó ní èémí ìyè nínú wọlé pẹ̀lú Nóà sínú ọkọ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 7

Jẹ́nẹ́sísì 7:5-17