Jẹ́nẹ́sísì 44:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí náà, bí a bá padà tọ baba wa lọ láì sí ọmọ náà pẹ̀lú wa-nígbà tí a mọ̀ pé, ọmọ náà ni ẹ̀mí baba wa.

Jẹ́nẹ́sísì 44

Jẹ́nẹ́sísì 44:23-34