Jẹ́nẹ́sísì 44:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ó bá ri pé ọmọkùnrin náà kò wá pẹ̀lú wa, yóò kú. Àwọn ìránṣẹ́ rẹ yóò wá mú baba wa t'òun ti ewú orí lọ sí ipò òkú ní ìbànújẹ́.

Jẹ́nẹ́sísì 44

Jẹ́nẹ́sísì 44:27-34