Jẹ́nẹ́sísì 44:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ẹ bá tún mú èyí lọ, kúrò lọ́dọ̀ mi, tí ohunkóhun bá ṣe é, ìbànújẹ́ ni ẹ ó fi mú ewú-orí mi lọ sí ipò òkú.’

Jẹ́nẹ́sísì 44

Jẹ́nẹ́sísì 44:23-33