Jẹ́nẹ́sísì 44:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà náà ni ó sọ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé, ‘Ẹ mu-un tọ̀ mí wá kí n le fojú ara mi rí i.’

Jẹ́nẹ́sísì 44

Jẹ́nẹ́sísì 44:19-22