Jẹ́nẹ́sísì 44:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì sọ fún olúwa à mi pé, ‘Ọmọkùnrin náà kò le è fi baba rẹ̀ sílẹ̀, bí ó bá dán-an wò baba rẹ̀ yóò kú.’

Jẹ́nẹ́sísì 44

Jẹ́nẹ́sísì 44:16-25