Jẹ́nẹ́sísì 41:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí odindi ọdún méjì sì ti kọjá, Fáráò lá àlá: ó rí ara rẹ̀ tó dúró ní etí odò Náílì.

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:1-9