Jẹ́nẹ́sísì 40:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n, olórí agbọ́tí kò rántí Jósẹ́fù mọ́, kò tilẹ̀ ronú nípa rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 40

Jẹ́nẹ́sísì 40:20-23