Jẹ́nẹ́sísì 41:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni màlúù méje jáde láti inú odò, wọ́n dára láti wò, wọ́n sì sanra, wọ́n sì ń jẹ koríko.

Jẹ́nẹ́sísì 41

Jẹ́nẹ́sísì 41:1-6