Jẹ́nẹ́sísì 40:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósẹ́fù dáhùn, “Èyí ni ìtúmọ̀ àlá rẹ. Agbọ̀n mẹ́ta náà túmọ̀ sí ọjọ́ mẹ́ta.

Jẹ́nẹ́sísì 40

Jẹ́nẹ́sísì 40:10-20