Jẹ́nẹ́sísì 40:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láàrin ọjọ́ mẹ́ta, Fáráò yóò tú ọ sílẹ̀, yóò sì bẹ́ orí rẹ, yóò sì gbé ara rẹ kọ́ sí orí igi. Àwọn ẹyẹ yóò sì jẹ ara rẹ.”

Jẹ́nẹ́sísì 40

Jẹ́nẹ́sísì 40:11-22