Jẹ́nẹ́sísì 40:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú agbọ̀n tí ó wà lókè, onírúurú oúnjẹ ló wà níbẹ̀ fún Fáráò, ṣùgbọ́n àwọn ẹyẹ sì ń ṣà wọ́n jẹ láti inú apẹ̀rẹ̀ náà tí ó wà lórí mi”

Jẹ́nẹ́sísì 40

Jẹ́nẹ́sísì 40:16-23