Jẹ́nẹ́sísì 4:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ádámù sì tún bá aya rẹ̀ lò pọ̀, ó sì bí ọmọkùnrin kan tí ó pe orúkọ rẹ̀ ní Ṣẹ́tì, tí ó túmọ̀ sí pé, “Ọlọ́run fún mi ní ọmọkùnrin mìíràn ní ipò Ábélì tí Káínì pa.”

Jẹ́nẹ́sísì 4

Jẹ́nẹ́sísì 4:16-26