Jẹ́nẹ́sísì 4:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lámékì wí fún àwọn aya rẹ̀,“Ádà àti Ṣílà, ẹ tẹ́tí sí mi;ẹ̀yin aya Lámékì, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi.Mo ti pa ọkùnrin kan tí ó kọlù mí,ọ̀dọ́mọkùnrin tí ó pa mí lára.

Jẹ́nẹ́sísì 4

Jẹ́nẹ́sísì 4:17-26