Jẹ́nẹ́sísì 4:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣílà náà sì bí ọmọkùnrin tí ń jẹ́ Tubali-Káínì, tí ó ń rọ oríṣìíríṣìí ohun èlò láti ara idẹ àti irin. Arábìnrin Tubali-Káínì ni Náámà.

Jẹ́nẹ́sísì 4

Jẹ́nẹ́sísì 4:19-26