Jẹ́nẹ́sísì 4:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Júbálì, òun ni baba irú àwọn tí ń tẹ dùùrù tí wọ́n sì ń fọn fèrè.

Jẹ́nẹ́sísì 4

Jẹ́nẹ́sísì 4:11-24