Jẹ́nẹ́sísì 4:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ádà sì bí Jábálì: òun ni baba irú àwọn tí ń gbé inú àgọ́, tí wọ́n sì ń sin ẹran-ọ̀sìn.

Jẹ́nẹ́sísì 4

Jẹ́nẹ́sísì 4:16-21