Jẹ́nẹ́sísì 4:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà, ó sì bí ọmọkùnrin mìíràn tí a pè ní Ábélì.Ábélì jẹ́ darandaran, Káínì sì jẹ́ àgbẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 4

Jẹ́nẹ́sísì 4:1-4