Jẹ́nẹ́sísì 4:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, Káínì mú ọrẹ wá fún Olúwa nínú èṣo ilẹ̀ rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 4

Jẹ́nẹ́sísì 4:1-7