Jẹ́nẹ́sísì 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ádámù sì bá aya rẹ̀ Éfà lò pọ̀, ó sì lóyún, ó sì bí Káínì. Ó wí pé, “Pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ Olúwa ni mo bí ọmọkùnrin.”

Jẹ́nẹ́sísì 4

Jẹ́nẹ́sísì 4:1-3