Jẹ́nẹ́sísì 39:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kan, Jósẹ́fù lọ sínú ilé láti ṣe iṣẹ́, kò sì sí èyíkéyìí nínú àwọn ìránṣẹ́ ní tòsí.

Jẹ́nẹ́sísì 39

Jẹ́nẹ́sísì 39:5-15