Jẹ́nẹ́sísì 39:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó tílẹ̀ jẹ́ pé gbogbo ìgbà ni ó ń tẹnumọ́ èyí fún Jósẹ́fù, Jósẹ́fù kọ̀ láti bá a lò pọ̀. Ó tilẹ̀ kọ̀ láti máa dúró ni ibi tí ó bá wà.

Jẹ́nẹ́sísì 39

Jẹ́nẹ́sísì 39:1-14