Jẹ́nẹ́sísì 39:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì di aṣọ Jósẹ́fù mú, ó sì wí pé, “Wá bá mi lò pọ̀!” Ṣùgbọ́n Jósẹ́fù fi aṣọ rẹ̀ sílẹ̀ sí i lọ́wọ́, ó sì sá jáde.

Jẹ́nẹ́sísì 39

Jẹ́nẹ́sísì 39:5-22