Jẹ́nẹ́sísì 37:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn arákùnrin rẹ̀ wí fún un pé, “Ìwọ ń gbérò àti jọba lé wa lórí bí? Tàbí ìwọ ó ṣe olórí wa ní tòótọ́?” Wọn sì túbọ̀ kórìíra rẹ̀ sí i, nítorí àlá rẹ̀ àti nítorí ohun tí ó wí.

Jẹ́nẹ́sísì 37

Jẹ́nẹ́sísì 37:2-14