Jẹ́nẹ́sísì 37:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sáà wò ó, àwa ń yí ìdì ọkà nínú oko, ó sì ṣe ìdì ọkà tèmi sì dìde dúró ṣánṣán, àwọn ìdì ọkà tiyín sì dòòyì yí tèmi ká, wọ́n sì ń foríbalẹ̀ fún un.”

Jẹ́nẹ́sísì 37

Jẹ́nẹ́sísì 37:5-17