Jẹ́nẹ́sísì 37:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O sì tún lá àlá mìíràn, ó sì tún sọ ọ́ fún àwọn arákùnrin rẹ̀. Ó wí pé, ẹ tẹ́tí sí mi, “Mo tún lá àlá mìíràn, wò ó, oòrùn, òṣùpá àti ìràwọ̀ mọ́kànlá ń forí balẹ̀ fún mi.”

Jẹ́nẹ́sísì 37

Jẹ́nẹ́sísì 37:1-13