Jẹ́nẹ́sísì 34:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ámórì àti Ṣékémù ọmọ rẹ̀ sì wá sí ẹnu ibodè ìlú náà wọn sì bá àwọn ará ìlú náà sọ̀rọ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 34

Jẹ́nẹ́sísì 34:10-28