Jẹ́nẹ́sísì 34:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wí pé, “Ìwa àwọn ọkùnrin wọ̀nyí dára, ẹ jẹ́ kí wọn máa gbé ní àárin wa, kí wọn sì máa ṣòwò, ilẹ̀ kúkú wà rẹpẹtẹ tó gbààyè dáradára. A lè fẹ́ àwọn ọmọ wọ̀n, ki wọn sì fẹ́ tiwa pẹ̀lú.

Jẹ́nẹ́sísì 34

Jẹ́nẹ́sísì 34:17-23