Jẹ́nẹ́sísì 34:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀dọ́mọkùnrin náà, ẹni tí ó jẹ́ ẹni iyì jùlọ ní ilé bàbá rẹ̀, kò jáfara láti ṣe ohun tí wọ́n wí. Nítorí tí ó fẹ́ràn ọmọbìnrin Jákọ́bù.

Jẹ́nẹ́sísì 34

Jẹ́nẹ́sísì 34:16-25