Jẹ́nẹ́sísì 32:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì dìde ní òru ọjọ́ náà, ó mú àwọn aya rẹ̀ méjèèjì, àwọn ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ méjèèjì, àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ mọ́kọ̀ọ̀kànlá, wọ́n sì kọjá ní ìwọdò Jábókù.

Jẹ́nẹ́sísì 32

Jẹ́nẹ́sísì 32:21-28