Jẹ́nẹ́sísì 32:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ìgbà tí ó ti rán wọn kọjá odò tán sí òkè-odò, ó sì rán àwọn ohun-ìní rẹ̀ kọjá pẹ̀lú.

Jẹ́nẹ́sísì 32

Jẹ́nẹ́sísì 32:22-27