Jẹ́nẹ́sísì 32:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà ẹ̀bùn Jákọ́bù ṣáájú rẹ̀ lọ, Jákọ́bù pàápàá sì lo òru ọjọ́ náà nínú àgọ́

Jẹ́nẹ́sísì 32

Jẹ́nẹ́sísì 32:13-26