Jẹ́nẹ́sísì 31:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mo ti wà lọ́dọ̀ rẹ fún ogún ọdún, àwọn àgùntàn tàbí ewúrẹ́ rẹ kò sọnù bẹ́ẹ̀ n kò pa ọ̀kan jẹ rí nínú àwọn àgbò rẹ.

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:28-42