Jẹ́nẹ́sísì 31:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò mú ọ̀kankan wá fún ọ rí nínú èyí tí ẹranko búburú fà ya, èmi ni ó fara mọ́ irú àdánù bẹ́ẹ̀. Ẹrankẹ́ran tí wọ́n bá sì jí lọ, lọ́sàn án tàbí lóru, ìwọ ń gba owó rẹ̀ lọ́wọ́ mi

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:35-42