Jẹ́nẹ́sísì 31:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsin yìí tí ìwọ ti tú gbogbo ẹrù mi wò, kín ni ohun tí í ṣe tirẹ̀ tí ìwọ rí? Kó wọn kalẹ̀ báyìí níwájú gbogbo ìbátan rẹ àti tèmi, kí wọn kí ó sì ṣe ìdájọ́ láàrin àwa méjèèjì.

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:36-46