Jẹ́nẹ́sísì 31:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú sì bí Jákọ́bù, ó sì pe Lábánì ní ìjà pé, “Kín ni ẹ̀ṣẹ̀ mi? Ẹ̀ṣẹ̀ wo ni mo ṣẹ̀ ọ tí ìwọ fi ń lépa mi bí ọ̀daràn?

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:30-44