Jẹ́nẹ́sísì 31:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síwájú sí i, Jákọ́bù tan Lábánì ará Árámù, nítorí kò sọ fún un wí pé òun ń sá lọ.

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:19-30