Jẹ́nẹ́sísì 31:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì sá lọ pẹ̀lú ohun gbogbo tí ó ni, ó sì la odò kọjá (Yúfúrátè), ó sì kọrí sí àwọn ilẹ̀ olókè ti Gílíádì.

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:17-26