Jẹ́nẹ́sísì 31:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Lábánì sì lọ láti rẹ́run àgùntàn, Rákélì sì jí àwọn ère òrìṣà ilé baba rẹ̀.

Jẹ́nẹ́sísì 31

Jẹ́nẹ́sísì 31:14-28