Jẹ́nẹ́sísì 29:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lábánì wí fún Jákọ́bù pé “Bí a tilẹ̀ jẹ́ ìbátan, kò yẹ kí o máa ṣiṣẹ́ fún mi lásán láìgba ohun kankan. Sọ ohun tì ìwọ fẹ́ gbà fún iṣẹ́ tí ìwọ ń ṣe fún mi!”

Jẹ́nẹ́sísì 29

Jẹ́nẹ́sísì 29:13-22